Lagbaja - Olagbaja Ma Tun De O lyrics
rate meO de o / Olagbaja ma tun de o / O bo sokoto k'enu e da'le / Olagbaja ma tun de o

Chant: Olagbaja nbe lode / Eru o le bawa o / Olagbaja nbe lode / Eru o le ba a o

Chant: Ko i ye won / Yio ye won lola

Chant: Olagbaja ma tun de o / O bo sokoto k'enu e da'le / Olagbaja ma tun de o

Chant: Wa fun wa nilu / Ilu orin / Wa fun wa ni'lu / Ilu orin