Lagbaja - Agidigbo lyrics
rate meAa, lowe lowe la mi nlulu agidigbo / Ologbon mi a gbo / Omoran lo ma ye / Ahaa, te'ti e sile ko o kogbon o / Ilu nro kango kango / Agidigbo nsoro / Oro ijinle / Ah, iwo nmi'ri / O nse beeni, beeni / Ose ayan / 'Mode yi oro lo so, oro lo so, oro lo so, oo puro o / Beeke oo gbo'lu / Oo gbo nothing / Beeke oo ma de gbo ohun t'aye nwi o / Nje ka loo gbo ni / Boya se loba yari pata / Ka loo gbo ni boya se lo ba ki ija mole / Ka loo gbo ni / Boya se lo ba so gele / Dooja o dain dain / Se pe ko lee dun ni / Ohun oluware o gbo / O ba f'eti sile / Ko ko die nibe / Boya won nbu e / Boya won nki e / Onilu yi sora e / Mama dogbon bu mi o / Ilu gbogbo ko loriki / Sora e / Ee, lowe lowe la mi nlulu agidigbo / Ologbon mi a gbo / Omoran lo ma ye / O ba te'ti e sile koo kogbon o / Agidigbo nsoro oro ijinle

Agidigbo Chants: Gbomo gbomo, gbomo gbomo / ana o gbe kan opelenge / Oni o gbe kan fati bum bum / Ojo ojokan nbo / O si maa gbe / O si maa gbe / Ojo ojokan o si maa gbe jombo

Fine baby to ndan / O kun soju / O kun sete / Lai sojuju Calabar / Mama mu mi dese mo niyawo mi sile / Mi o si le gboju / Mi o le gboju mi kuro / Boo ba be careful / Wa tele mi dele

E pagbo yimika / Agidigbo / Yimika / E pagbo yimikaa / Yimika / Ta lo nsoro / Nsoro / Ta lo Ngboro / Ngboro / Enit'o leti / To leti / To f'arabale / F'arabale /Ki lagidigbo wi / Gidigbo wi / Oro ijinle / Ijinle / E pagbo yimikaa / Agidigbo / Yimika / Agidigbo

O se mode yi / Nje ka loo gbo ni / Boya se lo be yari pata / Ka loo gbo ni / Boya se lo ba ki ija mole / Ka loo gbo ni / Boya se lo ba so gele dooja o dain dain /

Aaa agidigbo nsoro / Oro ijinle / Un hun, un hun, onilu yi sora e /Ah mama dogbon bu mi o / Mo mo pelu gbogbo ko loriki / Ayan sora e / Sora e, sora e o /

Mama dan mi wo / Ayan sora e / Aa, aa, agidigbo nsoro / Oro ijinle