Lagbaja - Ilu Ree O lyrics
rate meO loo moo jo / Ibo lo ti ja wa to o lokun lorun / Ibo lo ro po wa / To njiyan ijo / O ba koraa re sapakan o je nkoja lo / Odaa en, boo ba loo moo j / Oya bo sagbo / Ko wa dan'ra e wo / Ab'oo ti gbo? / Oo ti gbo nipa wa / Too m o ro po sese de ni / Mo ro po sese wo'lu / Ee / Beni / Oo mo nkan kan / Ki lo mo, to loo moo jo / Ibi o ba ti si'le / Won le moo jiyan ija / Ibi o ba ti si'lu / Won le moo jiyan ijo / Ilu ree o / Ile ree o / Ilu ree o / Ijo momo ree o / Ilu ree o / Agbo momo ree o / Ilu ree o / Ijo momo ree o / Eni laya ko bo sagbo

Chorus: Ilu ree o / Ijo momo ree o / Eni laya ko bo s'agbo

Ijo agba ni / Ijo agba ni / Ko si pakanleke / Ijo agba ni / Die, die / Die, die e rora

Aaa.. oun ni yen / Aa O seun / Oun ni yen

Chorus: Ilu ree o...

Ayan iwo da?